Erin-Osun Anthem

Erin ooo
Erin moje ooo
Erin moje omo saaja
Omo elewe 'ladogba
Erin moje olokiki
llu to gbaju gbaja lawujo
Tati n bimo atata
Ta ti n bimo olokiki. llu ologun abalaye
llu ibere awon akoni
Obalufon omo olu ife
To gbera n'ife to d'Erinmo
Lat'Erinmo to fi d'Erin-ljesa
Lat'ljesa to fi d'Erin-lle
Titi to fi gunle s'Erin-Osun
Bi won tipo to won o yarawon
Won fi'mo sokan, won s'asepo
Awa ola Erin oun re ooo
E je ka fowo s'owopo gbe Erin-Osun gaa
Orin:-
llu Erin yii ti gbogbo wa ni, ko ma gbodo bajee
E je ka s'owopo gbe Erin-Osun ga, gbee kemi gbee.

Pride Of Our Home

The spirit of unity forged by the early settlers has paved way for many epitomes of communal progress and development in all the length and breath of the town, hence the early construction of so many roads and bridges connecting the neighboring towns and villages together and the building of the modern Obas palace, first of its kind in the middle of seventies (1970’s). This attitude has helped to a large extent to improve the socio-economic activities of the town. Erin-Osun, one of the two (2) major towns in Irepodun Local Government Area of State of Osun, has so much honour. It is a land of brave warriors and believe so much in the tradition of “Justice and Equity”. ...read more

DID YOU KNOW?

more facts